Tipa tikuuku
Oluwa mu Mi lo shey rere
Tipa tikuuku
Oluwa mu Mi lo shey rere
Boya mofe
Boya Mo Ko
Oluwa mumi de’be
Omo Israeli Lojo yen oo
Tipa tikuuku na fi de’le Ileri
Obediedomu gba kamu
Opelope Apoti Eri
Josefu iba MA tayo
Biwon o ba ta leru Lojo yen
Oluwa lai first temi shey
Jowo mun MI de’bi Ogo.
DOWNLOAD MP3