Powerful Live song tagged Iriri, original song by Mr. Gbera featuring Adeyinka Alaseyori
Audio PlayerIru Iriri Lyrics ft Adeyinka Alaseyori
Eyi to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Iru iriri ti mori gba won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba
Ohun gbogbo to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Ohun toje ipalara fun won
ara irelofi jasi femi
tori moranugba ni
Ohun to lakoja to fa eri
lofa iku opolopo
oje dupe
Ona to hun lo to nmu onje wale
lomu opo lo orun oje dupe
Ona ofun re oda ona iku
oje dupe
Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe
Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba
Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba
Orisirisi iriri lohun sele
Aimoye nkan ta ogbori losele
Gbogbo orile ede ohun be ni titi
Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba