Home Nigeria Gospel Music Yoruba Gospel Music Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A Fasoyin

Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A Fasoyin

0

Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A FasoyinMrs D.A Fasoyin, a well-known gospel artist, presents a beautiful song called ‘Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re’ This song is a special way to show love and respect to God, with lovely and catchy music.

It’s not just regular music; it’s like a bridge that connects people to something heavenly. Enjoy this amazing musical journey, get this unique song, and share the joy with your friends and family.”

DOWNLOAD MP3

Ara mi yo ya gaga – C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Igbagbõ la fi n rire gba lõwõ Baba

F’igbagbõ rõ m’ęni to le gba õ, arakunrin

F’igbagbõ rõ m’ęni to le gba õ, arabinrin

Gba t’iji aye ba yi lu o, sa gbękęle

Ko gbogbo aniyan rę l’Oluwa, sa ti gbagbõ

Obinrin onisun ęję, to f’igbagbõ tõ Jesu wa nibę lo rire gba

Isun ęję si duro lai t’ori p’o gbagbõ

Ara rę si ya gaga, ara rę si ya gaga

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Nipa Igbagbõ, Abęli rubõ s’Õlõrun

Nipa igbagbõ, Enõku ba Õlõrun rin

Nipa igbagbõ, Abraham d’õrę Õlõrun

Nipa igbagbõ ni Noha d’olododo

O f’eti si õrõ Õlõrun

N’igba t’o kan õkõ igbala

Ikun omi de, õpõ si s’egbe

Kiki awõn to gbõ ti Noha nikan ni wõn la

Namani f’igbagbõ wę ninu omi, o d’asęgun

Iwõ arakunrin (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ arabinrin (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’ogun aye ba de (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’ogun õta ba de (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’owo lo n fę. (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’õmõ lo wu õ (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o ję ‘le lo fę kõ (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’owo lo fę se (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ ti ko ri ję (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ ti ko ri mu (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Agan ma ronu mõ(Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Babalawo ko le se

Onisegun ko le se

Adahunse ko le s’õmõ f’igbagbõ rõ m’Oluwa

Ninu Bibeli, Ana f’igbagbõ rõ m’Oluwa

Agan r’õmõ gba t’ori p’o gbagbõ

Õlõrun f’Ana l’õmõ ara rę si ya gaga

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f’õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga


Join our WHATSAPP WHATSAPP CHANNEL or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here